Ile isẹ ọlọpaa:n gbe Ọrẹkunrin Khadijat rẹlẹ ẹjọ ni Ọjọ Aje

By | July 13, 2018

23 total views, 3 views today

Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ kan tí wọ́n ti ń wá Khadijat tó jẹ́ ọmọ igbákeji gómínà tẹ́lẹ̀rí ní ìpínlẹ̀ Ondo, wọ́n bá òkú rẹ̀ ní ilé àfẹ́sọ́nà rẹ̀.

Loading...

Ọpọlọpọ iroyin lo n jẹyọ lori isekupani Khadijat Olubọyo, sugbon Ileese Olọpaa ni ipinlẹ Ondo ni awọn ko gba ọrọ ọrẹkunrin Khadijat gbọ wipe, oun kọ loun pa ọmọbinrin naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Leave a Reply

Your email address will not be published.

Loading...